Job 8:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bí wọ́n bá fà á tu kúrò ní ààyè rẹ̀, kò sí ẹni tí yóo mọ̀ pé ó wà níbẹ̀ rí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi o ba si pa a run kuro ni ipò rẹ̀, nigbana ni ipò na yio sẹ ẹ pe: emi kò ri ọ ri!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí ó bá sì pa á run kúrò ní ipò rẹ̀, nígbà náà ni ipò náà sẹ́ ẹ pé, ‘Èmi kò ri ọ rí!’