Job 8:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ayọ̀ ọrọ̀ rẹ̀ kò jù báyìí lọ, àwọn mìíràn óo dìde, wọn yóo sì gba ipò rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kiyesi eyi ni ayọ̀ ọ̀na rẹ̀ ati lati inu ilẹ li omiran yio ti hù jade wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kíyèsí i, ayé rẹ̀ gbẹ dànù àti lati inú ilẹ̀ ní irúgbìn òmìíràn yóò hù jáde wá.