Job 8:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí ó bá jẹ́ pé àwọn ọmọ rẹ dẹ́ṣẹ̀ ni, ó ti jẹ wọ́n níyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati awọn ọmọ rẹ ṣẹ̀ si i, o si gbá wọn kuro nitori irekọja wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí àwọn ọmọ rẹ̀ sẹ̀ sí i, ó sì gbá wọn kúrò nítorí àṣẹ wọn.