Job 9:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí pé ó ti fi ìjì tẹ̀ mí mọ́lẹ̀, ó sì sọ egbò mi di pupọ láìnídìí;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe o fi ẹ̀fufu nla ṣẹ mi tutu, o sọ ọgbẹ mi di pipọ lainidi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé òun yóò lọ̀ mi lúúlúú pẹ̀lú ìjì ńlá ó sọ ọgbẹ́ mi di pupọ̀ láìnídìí.