Job 9:23 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí nǹkan burúkú bá ṣẹlẹ̀, tí ó já sí ikú òjijì, a máa fi aláìṣẹ̀ ṣe ẹlẹ́yà ninu ìdààmú wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi jamba ba pa ni lojijì, yio rẹrin idanwo alaiṣẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí ìjàǹbá bá pani lójijì, yóò rẹ́rín-ín ìdàwọ́ aláìṣẹ̀.