Job 9:35 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kí n baà le sọ̀rọ̀ láìbẹ̀rù, nítorí mo mọ inú ara mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni emi iba sọ̀rọ, emi kì ba si bẹ̀ru rẹ̀; ṣugbọn kò ri bẹ̃ fun mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni èmi ìbá sọ̀rọ̀, èmi kì bá sì bẹ̀rù rẹ̀; ṣùgbọ́n bí ó tí dáré-ti mi, kò ri bẹ́ẹ̀ fún mi.