Joel 1:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ sọ fún àwọn ọmọ yín nípa rẹ̀, kí àwọn náà sọ fún àwọn ọmọ wọn, kí àwọn ọmọ wọn sì sọ fún àwọn ọmọ tiwọn náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ sọ ọ fun awọn ọmọ nyin, ati awọn ọmọ nyin fun awọn ọmọ wọn, ati awọn ọmọ wọn fun iran miràn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ sọ ọ́ fún àwọn ọmọ yín, ki àwọn ọmọ yín sọ fún àwọn ọmọ wọn, ki àwọn ọmọ wọn sọ fún àwọn ìran mìíràn.