Joel 1:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n ti run ọgbà àjàrà mi, wọ́n ti já àwọn ẹ̀ka igi ọ̀pọ̀tọ́ mi, wọ́n ti bó gbogbo èèpo ara rẹ̀, wọ́n ti wó o lulẹ̀, àwọn ẹ̀ka rẹ̀ sì ti di funfun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O ti pa àjara mi run, o si ti ya ẹ̀ka igi ọ̀pọtọ́ mi kuro, o ti bó o jalẹ, o si sọ ọ nù; awọn ẹ̀ka rẹ̀ li a si sọ di funfun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó ti pa àjàrà mi run, ó sì ti ya ẹ̀ka igi ọ̀pọ̀tọ́ mi kúrò, ó ti bò èèpo rẹ̀ jálẹ̀, ó sì sọ ọ́ nù; àwọn ẹ̀ka rẹ̀ ni a sì sọ di fun-fun.