Joel 2:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA ní, “Ẹ yipada sí mi tọkàntọkàn nisinsinyii, pẹlu ààwẹ̀, ẹkún ati ìkẹ́dùn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Njẹ nitorina nisisiyi, ni Oluwa wi, Ẹ fi gbogbo ọkàn nyin yipada si mi, ati pẹlu ãwẹ̀, ati pẹlu ẹkún, ati pẹlu ọ̀fọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Njẹ́ nítorí náà nísínsin yìí,” ni OLÚWA wí, “Ẹ fi gbogbo ọkàn yín yípadà sí mi, àti pẹ̀lú ààwẹ̀, àti pẹ̀lú ẹkún, àti pẹ̀lú ọ̀fọ̀.”