Joel 2:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà náà ni ara bẹ̀rẹ̀ sí ta OLUWA nítorí ilẹ̀ rẹ̀, ó sì ṣàánú fún àwọn eniyan rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni Oluwa yio jowú fun ilẹ rẹ̀, yio si kãnu fun enia rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ní OLÚWA yóò jowú fún ilẹ̀ rẹ̀, yóò sì káànú fún ènìyàn rẹ̀.