Joel 2:24 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo ibi ìpakà ni yóo kún fún ọkà, ìkòkò waini ati ti òróró yín yóo kún àkúnwọ́sílẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ilẹ ipakà yio kún fun ọkà, ati ọpọ́n wọnni yio ṣàn jade pẹlu ọti-waini ati ororo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ilẹ̀ ìpàkà yóò kún fún ọkà; àti ọpọ́n wọn nì yóò ṣàn jáde pẹ̀lú ọti wáìnì tuntun àti òróró.