Joel 3:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ fi irin ọkọ́ yín rọ idà, ẹ fi dòjé yín rọ ọ̀kọ̀, kí àwọn tí wọn kò lágbára wí pé, “Ọmọ ogun ni mí.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ fi irin ọkọ́ itulẹ̀ nyin rọ idà, ati dojé nyin rọ ọkọ̀: jẹ ki alailera wi pe, Ara mi le koko.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ fi irin itulẹ yín rọ idà, àti dòjé yín rọ ọ̀kọ̀. Jẹ́ kí aláìlera wí pé, “Ara mi le koko.”