Joel 3:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ yára, ẹ wá, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè tí ẹ wà ní àyíká, ẹ parapọ̀ níbẹ̀. Rán àwọn ọmọ ogun rẹ wá, OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ kó ara nyin jọ, si wá, gbogbo ẹnyin keferi, ẹ si gbá ara nyin jọ yikakiri: nibẹ̀ ni ki o mu awọn alagbara rẹ sọkalẹ, Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ wá kánkán, gbogbo ẹ̀yin aláìkọlà láti gbogbo àyíká, kí ẹ sì gbá ara yín jọ yí káàkiri: Níbẹ̀ ní kí o mú àwọn alágbára rẹ ṣọkalẹ̀, OLÚWA.