Joel 3:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Jẹ́ kí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè dìde, kí wọ́n wá sí àfonífojì Jehoṣafati, nítorí níbẹ̀ ni n óo ti ṣe ìdájọ́ gbogbo orílẹ̀-èdè tí ó wà ní àyíká.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ ji, ẹ si goke wá si afonifojì Jehoṣafati ẹnyin keferi: nitori nibẹ̀ li emi o joko lati ṣe idajọ awọn keferi yikakiri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ẹ jí, ẹ sì gòkè wá sí àfonífojì Jéhóṣáfátì ẹ̀yin aláìkọlà: nítorí níbẹ̀ ní èmi yóò jòkòó láti ṣe ìdájọ́ àwọn aláìkọlà yí kákìri.