Joel 3:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ ti dòjé bọ oko, nítorí àkókò ìkórè ti tó, ẹ lọ fún ọtí waini nítorí ibi ìfúntí ti kún. Ìkòkò ọtí ti kún àkúnwọ́sílẹ̀, nítorí ìkà wọ́n pọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ tẹ̀ doje bọ̀ ọ, nitori ikore pọ́n: ẹ wá, ẹ sọkalẹ; nitori ifunti kún, nitori awọn ọpọ́n kún rekọja, nitori ìwa-buburu wọn pọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ tẹ̀ dòjé bọ̀ ọ́, nítorí ìkórè pọ́n: ẹ wá, ẹ ṣọ̀kalẹ̀; nítorí ìfúntí kún, nítorí àwọn ọpọ́n kún-à-kún-wọ́sílẹ̀ nítorí ìwà búburú wọn pọ̀!”