Joel 3:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Ijipti yóo di aṣálẹ̀; Edomu yóo sì di ẹgàn, nítorí ìwà ipá tí wọ́n hù sí àwọn ará Juda, nítorí wọ́n ti pa àwọn aláìṣẹ̀ ní ilẹ̀ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Egipti yio di ahoro, Edomu yio si di aginju ahoro, nitori ìwa ipá si awọn ọmọ Juda, nitoriti nwọn ti ta ẹjẹ̀ alaiṣẹ̀ silẹ ni ilẹ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n Éjíbítì yóò di ahoro, Édómù yóò sì di aṣálẹ̀ ahoro, nítorí ìwà ipá tí a hù sì àwọn ọmọ Júdà, ní ilẹ̀ ẹni tí wọ́n ti ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀.