Joel 3:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn àwọn eniyan yóo máa gbé ilẹ̀ Juda títí lae, wọn óo sì máa gbé ìlú Jerusalẹmu láti ìrandíran.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn Juda yio joko titi lai, ati Jerusalemu lati iran de iran.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n Júdà yóò jẹ́ ibùgbé títí láé, àti Jérúsálẹ́mù láti ìran dé ìran.