Joel 3:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
N óo gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ àwọn tí ẹ pa, n kò sì ní dá ẹlẹ́bi sí, nítorí èmi OLUWA ni mò ń gbé Sioni.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori emi o wẹ̀ ẹjẹ̀ wọn nù, ti emi kò ti wẹ̀nu: nitori Oluwa ngbe Sioni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí èmi yóò wẹ ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ wọn nù, tí èmi kò tíì wẹ̀nù. Nítorí OLÚWA ń gbé Síónì.”