Joel 3:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ ta àwọn ará Juda ati àwọn ará Jerusalẹmu fún àwọn ará Giriki, ẹ kó wọn jìnnà réré sí ilẹ̀ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọmọ Juda, ati awọn ọmọ Jerusalemu li ẹnyin ti tà fun awọn ara Griki, ki ẹnyin ba le sìn wọn jina kuro li agbègbe wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti àwọn ọmọ Júdà, àti àwọn ọmọ Jérúsálẹ́mù ní ẹ̀yin ti tà fún àwọn ara Gíríkì, kí ẹ̀yin báà le sí wọn jìnnà kúrò ní agbègbè ilẹ̀ ìnì wọn.