Joel 3:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ kéde èyí láàrin gbogbo orílẹ̀-èdè. Ẹ múra ogun, ẹ rú àwọn akọni sókè. Kí gbogbo àwọn ọmọ ogun súnmọ́ tòsí, ogun yá!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ kede eyi li ãrin awọn keferi; ẹ yà ogun si mimọ́, ẹ ji awọn alagbara, ẹ sunmọ tòsi, ẹ goke wá gbogbo ẹnyin ọkunrin ologun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ kéde èyí ní àárin àwọn aláìkọlà; Ẹ dira ogun, ẹ jí àwọn alágbára, Jẹ kí awọn ajagun kí wọn bẹ̀rẹ̀ ogun,