John 1:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó sọ òtítọ́, kò parọ́, ó ní, “Èmi kì í ṣe Mesaya náà.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si jẹwọ, kò si sẹ́; o si jẹwọ pe, Emi kì iṣe Kristi na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òun kò sì kùnà láti jẹ́wọ́, ṣùgbọ́n òun jẹ́wọ́ wọ́ọ́rọ́wọ́ pé, “Èmi kì í ṣe Kírísítì náà.”