John 12:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn Giriki mélòó kan wà ninu àwọn tí ó gòkè lọ sí Jerusalẹmu láti jọ́sìn ní àkókò àjọ̀dún náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn Hellene kan si wà ninu awọn ti o gòke wá lati sìn nigba ajọ:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn Gíríkì kan sì wà nínú àwọn tí ó gòkè wá láti sìn nígbà àjọ: