John 13:37 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Peteru bi í pé, “Oluwa, kí ló dé tí n kò lè tẹ̀lé ọ nisinsinyii? Mo ṣetán láti kú nítorí rẹ.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Peteru wi fun u pe, Oluwa, ẽṣe ti emi ko fi le tọ̀ ọ nisisiyi? emi o fi ẹmí mi lelẹ nitori rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Pétérù wí fún un pé, “Olúwa èése tí èmi kò fi le tọ̀ ọ́ nísinsìn yìí? Èmi ó fi ẹ̀mi mi lélẹ̀ nítorí rẹ.”