John 14:30 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
N kò tún ní ohun pupọ ba yín sọ mọ́, nítorí aláṣẹ ayé yìí ń bọ̀. Kò ní agbára kan lórí mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi kì o ba nyin sọ̀rọ pipọ: nitori aladé aiye yi wá, kò si ni nkankan lọdọ mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi kì ó bá yín sọ̀rọ̀ púpọ: nítorí aláde ayé yí wá, kò sì ní nǹkankan lọ́dọ̀ mi.