John 19:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà náà ni Pilatu mú Jesu, ó ní kí wọ́n nà án.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
NITORINA ni Pilatu mu Jesu, o si nà a.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà ni Pílátù mú Jésù, ó sì nà án.