John 19:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí Pilatu gbọ́ gbolohun yìí, ẹ̀rù túbọ̀ bà á.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina nigbati Pilatu gbọ́ ọ̀rọ yi ẹ̀ru tubọ ba a.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà nígbà tí Pílátù gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ẹ̀rù túbọ̀ bà á.