John 20:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
(Nítorí ohun tí Ìwé Mímọ́ wí kò tíì yé wọn pé dandan ni kí ó jí dìde ninu òkú.)
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe nwọn kò sá ti imọ̀ iwe-mimọ́ pe, on kò le ṣaima jinde kuro ninu okú.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
(Nítorí tí wọn kò sáà tí mọ ìwé mímọ́ pé, òun ní láti jíǹde kúrò nínú òkú.)