John 3:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
(Wọn kò ì tíì ju Johanu sẹ́wọ̀n ní àkókò yìí.)
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoriti a kò ti isọ Johanu sinu tubu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí tí a kò tí ì sọ Jòhánù sínú túbú.