John 6:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí ilẹ̀ ṣú, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sọ̀kalẹ̀ lọ sí èbúté,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati alẹ si lẹ, awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ lọ sinu okun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí alẹ́ sì lẹ́, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sọ̀kalẹ̀ lọ sí òkun.