John 6:59 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Jesu sọ ọ̀rọ̀ yìí nígbà tí ó ń kọ́ àwọn eniyan ninu ilé ìpàdé wọn ní Kapanaumu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nkan wọnyi li o sọ ninu sinagogu, bi o ti nkọni ni Kapernaumu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nǹkan wọ̀nyí ni ó sọ nínú sínágọ́gù, bí ó ti ń kọ́ni ní Kápánámù.