John 6:67 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Jesu bá bi àwọn ọmọ-ẹ̀yìn mejila pé, “Ẹ̀yin náà fẹ́ lọ bí?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina Jesu wi fun awọn mejila pe, Ẹnyin pẹlu nfẹ lọ bi?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà Jésù wí fún àwọn méjìlá pé, “Ẹ̀yin pẹ̀lú ń fẹ́ lọ bí?”