John 7:41 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn mìíràn ń sọ pé, “Òun ni Mesaya.” Ṣugbọn àwọn mìíràn ń sọ pé, “Báwo ni Mesaya ti ṣe lè wá láti Galili?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn miran wipe, Eyi ni Kristi na. Ṣugbọn awọn kan wipe Kinla, Kristi yio ha ti Galili wá bi?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn mìíràn wí pé, “Èyí ni Kírísítì náà.” Ṣùgbọ́n àwọn kan wí pé kínla, “Kírísítì yóò ha ti Gálílì wá bí?