John 7:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
(Àwọn arakunrin rẹ̀ kò gbà á gbọ́ ni wọ́n ṣe sọ bẹ́ẹ̀.)
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe awọn arakunrin rẹ̀ kò tilẹ gbà a gbọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé àwọn arákùnrin rẹ̀ pàápàá kò tilẹ̀ gbàágbọ́.
Recommended Reading