Jonah 1:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n bèèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé: “Kí ni kí á ṣe sí ọ, kí ìjì omi òkun lè dáwọ́ dúró? Nítorí ìjì náà sá túbọ̀ ń le sí i ni.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni nwọn wi fun u pe, Kini ki a ṣe si ọ, ki okun le dakẹ fun wa? nitori okun ru, o si jà ẹfufu lile.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni wọ́n wí fún un pé, “Kí ni kí àwa ó se sí ọ kí òkun lè dákẹ́ fún wa?” Nítorí òkun ru, ó sì ja ẹ̀fúùfù líle.