Jonah 1:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ̀rù OLUWA ba àwọn tí wọ́n wà ninu ọkọ̀ lọpọlọpọ, wọ́n rúbọ, wọ́n sì jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni awọn ọkunrin na bẹ̀ru Oluwa gidigidi, nwọn si rubọ si Oluwa, nwọn si jẹ́ ẹ̀jẹ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni àwọn ọkùnrin náà bẹ̀rù OLÚWA gidigidi, wọn si rúbọ sí OLÚWA, wọ́n sì jẹ́ ẹ̀jẹ́.