Jonah 1:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA bá pèsè ẹja ńlá kan tí ó gbé Jona mì. Jona sì wà ninu ẹja náà fún ọjọ́ mẹta.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn Oluwa ti pese ẹja nla kan lati gbe Jona mì. Jona si wà ninu ẹja na li ọsan mẹta ati oru mẹta.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n OLÚWA ti pèṣè ẹja ńlá kan láti gbé Jónà mì. Jónà sì wà nínú ẹja náà ni ọ̀sán mẹ́ta àti òru mẹ́ta.