Joshua 1:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n dá Joṣua lóhùn pé, “Gbogbo ohun tí o pa láṣẹ fún wa ni a óo ṣe, ibikíbi tí o bá sì rán wa ni a óo lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn si da Joṣua lohùn, wipe, Gbogbo ohun ti iwọ palaṣẹ fun wa li awa o ṣe, ibikibi ti iwọ ba rán wa lọ, li awa o lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni wọ́n dá Jósúà lóhùn pé, “Ohunkóhun tí ìwọ pa láṣẹ fún wa ni àwa yóò ṣe; ibikíbi tí ìwọ bá rán wa ni àwa yóò lọ.