Joshua 1:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Múra, kí o sì ṣe ọkàn gírí, nítorí ìwọ ni o óo jẹ́ kí àwọn eniyan wọnyi gba ilẹ̀ tí mo ti búra fún àwọn baba wọn, pé n óo fún wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣe giri, ki o si mu àiya le: nitori iwọ ni yio pín ilẹ na fun awọn enia yi, ilẹ ti mo ti bura fun awọn baba wọn lati fi fun wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Jẹ́ alágbára, kí o sì mú àyà le; nítorí ìwọ ni yóò ṣe amọ̀nà àwọn ènìyàn wọ̀nyí; láti lè jogún ilẹ̀ tí mo ti búra fún àwọn baba ńlá a wọn láti fi fún wọn.