Joshua 10:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Joṣua jálù wọ́n lójijì, lẹ́yìn tí ó ti fi gbogbo òru rìn láti Giligali.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Joṣua si yọ si wọn lojijì; o si gòke lati Gilgali lọ ni gbogbo oru na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n ti wọ́de ogun ní gbogbo òru náà láti Gílígálì, Jóṣúà sì yọ sí wọn lójijì.