Joshua 13:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mose fún àwọn ẹ̀yà Reubẹni ní ilẹ̀, gẹ́gẹ́ bí iye ìdílé wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mose si fi fun ẹ̀ya awọn ọmọ Reubeni, gẹgẹ bi idile wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èyí ni Mósè fi fún ẹ̀yà Rúbẹ́nì ni agbo ilé sí agbo ilé: