Joshua 15:32 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lebaotu, Ṣilihimu, Aini ati Rimoni; gbogbo ìlú ati ìletò wọn jẹ́ mọkandinlọgbọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Lebaotu, ati Ṣilhimu, ati Aini, ati Rimmoni: gbogbo ilu na jasi mọkandilọgbọ̀n, pẹlu ileto wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lébáótì, Sílímù, Háínì àti Rímónì, àpapọ̀ ìlú mọ́kàndín ní ọgbọ̀n àti àwọn ìlétò wọn.