Joshua 15:36 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣaaraimu, Aditaimu, Gedera, Gederotaimu; gbogbo ìlú ati ìletò wọn jẹ́ mẹrinla.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Ṣaaraimu, ati Aditaimu, ati Gedera, ati Gederotaimu; ilu mẹrinla pẹlu ileto wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣááráímù, Ádítaímù àti Gédérà (tàbí Gérérótíámù), ìlú mẹ́rìnlá àti àwọn ìletò wọn.