Joshua 15:44 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Akisibu, ati Mareṣa; gbogbo ìlú ati ìletò wọ́n jẹ́ mẹsan-an.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Keila, ati Aksibu, ati Mareṣa; ilu mẹsan pẹlu ileto wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kéílà, Ákísíbì àti Máréṣà, ìlú mẹ́sàn àti àwọn ìletò wọn. (9)