Joshua 15:48 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ìlú tí wọ́n wà ní orí òkè nìwọ̀nyí: Ṣamiri,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ni ilẹ òke, Ṣamiri, ati Jattiri, ati Soko;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ilẹ̀ òkè náà: Ṣámírì, Játírì, Sókò,