Joshua 15:51 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Goṣeni, Holoni, ati Gilo; gbogbo ìlú ati ìletò wọn jẹ́ mọkanla.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Goṣeni, ati Holoni, ati Gilo; ilu mọkanla pẹlu ileto wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gósénì, Hólónì àti Gílónì, ìlú mọ́kànlá àti ìletò wọn.