Joshua 15:54 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kiriati Ariba (tí à ń pè ní Heburoni), ati Siori, gbogbo ìlú ati ìletò wọn jẹ́ mẹsan-an.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Humta, ati Kiriati-arba (ti iṣe Hebroni), ati Siori; ilu meṣan pẹlu ileto wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Húmútà, Kíríátì Áríbà (tí í se, Hébúrónì) àti Síori: ìlú mẹ́sàn án àti àwọn ìletò rẹ̀