Joshua 15:59 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Maarati, Betanotu, ati Elitekoni, gbogbo ìlú ati ìletò wọn jẹ́ mẹfa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati Maarati, ati Beti-anotu, ati Eltekoni; ilu mẹfa pẹlu ileto wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Máárátì, Bẹti-Ánótì àti Élítékónì: ìlú mẹ́fà àti àwọn ìletò wọn.