Joshua 15:60 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kiriati Baali (tí wọn ń pè ní Kiriati Jearimu), ati Raba, gbogbo ìlú ati ìletò wọn jẹ́ meji.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kiriati-baali (ti iṣe Kiriati-jearimu), ati Rabba; ilu meji pẹlu ileto wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kiriati Báálì (tí í ṣe, Kiriati Jeárímù) àti Rábà ìlú méjì àti ìletò wọn.