Joshua 17:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn àwọn ọmọ Manase kò lè gba àwọn ìlú náà, àwọn ará Kenaani sì ń gbé ilẹ̀ náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn awọn ọmọ Manasse kò le gbà ilu wọnyi; awọn ara Kenaani si ngbé ilẹ na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣíbẹ̀, àwọn ọmọ Mánásè kò lè gba àwọn ìlú wọ̀nyí, nítorí àwọn ará Kénánì ti pinnu láti gbé ní ilẹ̀ náà.