Joshua 17:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn nígbà tí àwọn ọmọ Israẹli di alágbára, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí fi tipátipá mú àwọn ará Kenaani sìn, wọn kò sì lé wọn jáde patapata.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe, nigbati awọn ọmọ Israeli ndi alagbara, nwọn mu awọn ara Kenaani sìn, ṣugbọn nwọn kò lé wọn jade patapata.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n nígbà tí àwọn ará Ísírẹ́lì di alágbára, wọ́n mú àwọn ọmọ Kénánì sìn, ṣùgbọ́n wọn kò lé wọn jáde pátapáta.